Fake News: BBC kọ́ lọ́ ṣe ètò ìrànwọ́ ìwé kíkà Oríṣun àwòrán, Facebook
Àkọlé àwòrán, Àwọn èèyàn ti ń fi àlàyé arawọn sílẹ̀ lórí òpó náà, ṣùgbọ́n BBC kò mọ̀ nípa ètò ìrànwọ́ ìkàwé kankan tó jọ mọ́ bẹ́ẹ̀ 25 Sẹ́rẹ́ 2019
Ìròyìn òfegè ni ìròyìn tó ń lọ pé iléeṣẹ́ BBC ń ṣe ètò ìrànwọ́ ìwé kíkà lóríi www.giveaway-bbc.com.
Àwọn èèyàn ti ń lọ sí orí òpó ayélujára ọ̀hún àti òpó Facebook rẹ̀, https://www.facebook.com/GiveawayBBC/ tipẹ́.
Ṣùgbọ́n ilé iṣẹ́ BBC kò ní nǹkankan ṣe pẹ̀lú òpó náà.
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Play video, "BBC Yoruba ń pè yín sí ìpàdé ìtagbangba", Duration 0,51 00:51 Àkọlé fídíò, ìpàdé ìtagbangba ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú àwọn olùdíje sípò gomina ní ìpínlẹ̀ Eko. Eléyìí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìròyìn òfegè tí àwọn èèyàn ń gbé ka lóde òní.
A rọ àwọn èèyàn kí wọ́n mọ̀ dájú pe ilé iṣẹ́ BBC kò ní nǹkankan ṣe pẹ̀lú òpó náà.
Nigba kigba ti BBC ba fẹ ṣe eto ni a maa n gbee soju opo wa ni bbcnewsyoruba lori facebook ati instagram pelu lori www.bbc.com/yoruba lori ikanni website wa.
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Play video, "Àrà méèrírí , ẹ wo ọkùnrin tí eegun rẹ̀ rọ̀ bíi rọ́bà, tó ń ká bíi ẹja", Duration 1,00 01:00 Àkọlé fídíò, Murphy Elégungun Rọba: Mo fẹ́ di ẹnití egungun rẹ rọ jùlọ ní àgbáyé Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Play video, "Ṣé o lè dìbò fún olùdíje obìnrin? #BBCNigeria2019", Duration 2,15 02:15 Àkọlé fídíò, 'Obìnrin ló ni ilé àti àdúgbò fún ìdí èyí wọ́n lè ṣe ìlú dáadáa' Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Play video, "Exclusive: Tí a bá gbé ẹ̀ṣẹ̀ àwọn tó ń ṣèjọba lọ́wọ́ jáde, wọn yóò wọná - Obasanjo", Duration 9,25 09:25 Àkọlé fídíò, Obasanjo: Atiku kìí se Áńgẹ́lì, àmọ́ yóò se dáadáa ní ìlọ́po méjì ju Buhari lọ