El-Zakzaky: Ṣé lóòtọ́ ni ìjọba ń ná N3.5 mílíọ̀nù lórí aṣíwájú ẹ̀sìn Shiite lóṣù?

Lai Mohammed

Oríṣun àwòrán, @FMICNigeria

Àkọlé àwòrán, Lai ni aye ọba ni adari ijọ ẹsin Shiite lorilẹede Naijiria, Ibrahim El-Zakzaky n jẹ lahamọ
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Ni ọjọru ni iroyin kan jade pé minisita fun eto iroyin ati aṣa lorilẹ-ede Naijiria, Lai Mohammed ṣalaye fun awọn oniroyin pe miliọnu mẹta abọ naira ni ijọba apapọ fi n yanju ọrọ ounjẹ fun adari ijọ ẹsin Shiite lorilẹ-ede Naijiria, Ibrahim El-Zakzaky loṣu.

Minisita Lai Mohammed to n laa ye awọn akọroyin pe ijọba ko ṣa deede fi Ibrahim El-Zakzaky si ahamọ bikoṣe nitori pe ile ẹjọ ti o n gbọ ẹjọ rẹ ni ki wọn fi si ahamọ eyi to mu ki ileeṣẹ ọtẹlẹmuyẹ orilẹ-ede Naijiria o fi pamọ sinu ile kan ni ilu Abuja nibiti o ni ijọba ti n na owo to to miliọnu mẹta abọ ni ijọba apapọ lati fi gbọ bukata rẹ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àkọlé fídíò, Ìnú mi kìí dùn nígbà trí mo ń ṣiṣẹ́ ni bánkì tó ìgbà ti mo bẹ̀rẹ̀ mẹkáníìkì

Ọrọ yii ti wa di alatagba laarin awọn Ọmọ orilẹ-ede Naijiria bayii.

Ọgbẹni Reno Omokri to figbakan ri jẹ amugbalẹgbẹ fun aarẹ ana, Goodluck Jonathan ninu ọrọ tirẹ ni irọ nla ni minisita lai Mohammed pa.

Ninu ọrọ kan to kọ lori ikanni twitter rẹ, Omokri ni: "N3.5 miliọnu loṣu lati bọ Ibrahim El-Zakzaky tumọ si ẹgbẹrun lọna mẹrindinlọgọfa (N116,000) lojumọ. Nibo ni @Mbuhari ti ri onirọ nla bayii?

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Ni tirẹ, ọmọ ile igbimọ aṣofin agba, Ben Murray Bruce ni, "Bi aarẹ @Mbuhari ba lee na N3.5 miliọnu lati bọ Ibrahim El-Zakzaky loṣu, ko si idi ti ko yẹ ko ri ọgbọn ẹgbẹrun naira, N30, 000 lati san owo oṣu oṣi'\sẹ to kere ju lọ. Abi ki gbogbo oṣiṣẹ darapọ mọ Ibrahim El-Zakzaky lahamọ ni ki wọn lee maa gba ẹgbẹrun lọna mẹrindinlọgọfa (N116,000) lojumọ."

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 2

Ọkan o jọkan awọn ọmọ orilẹede Naijiria nile ati loke okun ni wọn ti n sọrọ lori ọrọ yii.

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3

Skip X post, 4

End of X post, 4