Adeleke: Ìjọba Ọ̀sun kò fẹ́ gbọ́ pé ebi ń pa araàlú ni mo se padà sí PDP
Sẹnetọ Ademola Adeleke to n dije dupo gomina ni ipinlẹ Osun sọ wi pe iya to n jẹ awọn ara ilu lo jẹ ki ohun jade lati du ipo.
Adeleke sọ eyi lasiko to n ba BBC Yoruba sọrọ, saaju idibo gomina ti yoo waye ni ọjọ Satide, ọjọ kejilelogun, Osu Kẹsan, ọdun yii ni ipinlẹ Osun.
O fikun wipe, ti oun ba di gomina ipinlẹ Osun, osoosu ni oun yoo maa jabọ fun awọn eniyan ipinlẹ Osun, ki wọn le mo ibi ti wọn ba ise de.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Àwọn ohun tó yẹ kó o mọ̀ nípa Adémọ́lá Adélékè
- 'Due Process ni mo fẹ́ tẹ̀lé láti gbọn ìyà Ọṣun nù'
- 'A máa bá àwọn èèyàn Ọṣun kọ́ ilé àkọ́tì wọn parí'
- Arẹgbẹsọla fowó lé isẹ́ àgbàse ní ìlọ́po márùn-ún - Omisore
- Ìpínlẹ̀ Oṣun kò nílò Gómìnà oníjó - Oshiomole
- Ijó Ademọla Adeleke rèé níbi ìpolongo ìbò PDP l‘Ọ́sun