OsunDecides: Adeleke kò jáwọn olólùfẹ́ tó fẹ́ wòran ijó rẹ̀ kulẹ̀

Àkọlé fídíò, OsunDecides: Adeleke kò jáwọn olólùfẹ́ tó fẹ́ wòran ijó rẹ̀ kulẹ̀

Oludije fun ipo gomina labẹ ẹgbẹ oselu PDP nipinlẹ Ọsun, Sẹnetọ Ademọla Adeleke, kò jáwọn olólùfẹ́, tó fẹ́ wòran ijó rẹ̀ kulẹ̀, lasiko eto ipolongo ibo rẹ to waye nilu Osogbo lọjọ̀ru.

Laarin awọn eekan ilu bii olori ile asofin agba, Bukọla Saraki ati alaga ẹgbẹ oselu PDP lorilẹ-ede yii, Uche Secondus, ti wọn peju sibi asekagba eto ipolongo ibo ọhun, ni Adeleke ti gba ijo.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: