Kunle Fela Anikulapo-Kuti: Olótìítọ́ ni Fẹla

Àkọlé fídíò, Irú ẹ̀dá wo ni Fẹla Jẹ́?

Ó pé ọdún méjìlélógún báyìí tí abàmì ẹ̀dá Fẹla Anikulapo Kuti re 'bi àgbà ń re ní ọjọ́ kejì oṣù kẹjọ ọdún 1997.

Ọpọlọpọ ni ko lee gbagbe Fela ati ipa ti o ko loke eepẹ nigba to wa laye ni Naijiria koda ni gbogbo agbaye.

Fẹla papòdà
Àkọlé fídíò, Lẹ́yín ọpọ̀lọpọ̀ ọdún, Lagbaja da ìlù bolẹ̀ nílú Abuja

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: