Davido, Simi,Omawumi gbégba orókè nínú ìdíje 2018

Àwòrán Simi, Davido àti Omawumi

Oríṣun àwòrán, Simi/Davido/Omawumi/Instagram

Àkọlé àwòrán, Ọ̀kẹ́ àìmọye olórin lo kópa níbi igbami ẹyẹ 'Headies' elekeejila tí ọdún 2018.
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Àwọn ọmọ tó jáwé olúborí ní 'Headies' 2018

Ọ̀kẹ́ àìmọye olórin lo kópa níbi igbami ẹyẹ headies elekeejila tí ọdún 2018.Ṣùgbọ́n Simisola Bolatito Ogunleye (Simi), David Adedeji Adeleke (Davido) àti Omawumi Megbele (Omawumi) lọ gbegba oroke níbi ayẹyẹ náà. Láti ọdún 2006 ni 'Headies' tí ń fáwọn to bá pegede nínú ìṣe orin takasufe lami ẹyẹ lorile-ede Naijiria.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Simi gba àmì ẹyẹ to dára ju lọ nínú RnB nínú orin adako rẹ 'Smile For Me' 'Joromi' bákan naa lọ gba Aliboomu tí dára julọ. Davido gba àmì ẹyẹ olórin to gbayii julọ àti orin to gbayii.

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 2

Nígbà tí Omawumi gbá àmì ẹyẹ obìnrin tó ní ohun tó dùn julọ ninu orin rẹ 'Butterfly'.