Olórí ilé aṣòfin ìpínlẹ Ọyọ, Michael Adeyemo jáde láyé

Michael Adeyemo

Oríṣun àwòrán, facebook/Michael Adeyemo

Àkọlé àwòrán, Abẹnugan ilé aṣòfin ipinlẹ Ọyọ, Michael Adeyemo jáde láyé

Olori ile aṣofin ipinlẹ Ọyọ, Aṣofin Michael Adeyemo ni iroyin sọ pe o ti jade laye.

Ninu ọrọ to ba BBC yoruba sọ, akọwe ipolongo fun ẹgbẹ oṣelu APC ni ipinlẹ Ọyọ, ọgbẹni Mojeed Olaoya, ṣalaye wi pe, ko tii si ẹni tó le sọ pato ohun to ṣokunfa iku rẹ, ṣugbọn o fọwọ rọri ku ni.

Lasiko ti a fi n ko iroyin yii jọ, wọn ti gbe oku aṣofin Michael Adeyemo lo si ile igbokusi.

Ile aṣofin ipinlẹ Ọyọ ko tii fi iroyin sita lori iku rẹ.

Ẹkunrẹrẹ iroyin laipẹ...