Dino: ọlọ́pàá yí ilé mi ká

Oríṣun àwòrán, Twitter/Dino Melaye
Lori ọrọ Senatọ Dino Melaye àti ilé iṣẹ ọlọ́pàá labuja ọrọ tun gba ibo míràn yo.
Lẹyin ti ile iṣẹ ọlọ́pàá tu Dino silẹ l'owurọ ọjọ ajé,o gbà ojú òpó Twitter re lati kéde pé àwọn ọlọpaa bi ogbon ti won dirá ogún tí yika ilé rẹ.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 1
Koda o tun fi awọran awọn ọkọ ọlọ́pàá sọwọ pẹlu ikede naa
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 2
Ṣugbọn Ọ́gá àgbà iléesẹ́ ọlọ́pàá fún ẹkùn keje,Ọ̀gbẹ́ni Istifanus Sunday Bako sọ fun BBC pé kò sí ootọ nínú ọrọ naa."A ti tú Dino silẹ lataaro. Mi o mo ibi to wa ṣugbọn ọlọ́pàá ko ragba di ile re"L'owurọ ọjọ ajé ni àwọn ọlọpaa mu Sẹnetọ Melaye ni papakọ ofurufu Nnamdi Azikiwe nilu Abuja.