Àwa ni à ń rọ gbogbo ǹkan ogun tí àwọn Basorun Ogunmola atàwọn akínkanjú Ibadan n lò nígbà náà- Hamzat Olaogun Adodo
Wo àgbẹ̀dẹ àkọkọ ní Ìbàdàn...
Ibadan ni agbẹdẹ akọkọ naa wa ni ipinle Oyo to wa ni Iwo oorun guusu Naijira- Idile Adodo
Idile Adodo ni awọn ni agbẹdẹ akọkọ ni iwọ oorun guusu Naijiria, bẹẹ si ni idile wọn lo ma n rọ ibon ati ọta fun awọn jagunjagun latijọ.
Bakan naa ni Aṣofin Nurudeen Raji to jẹ ọkan lara awọn ọmọ inu ile Alagbede Adodo naa ba BBC Yoruba sọrọ to fi ṣalaye bi wọn ṣe n ṣe iṣẹ rirọ nkan ijagun nigba naa.
Iru awọn iroyin ti ẹ le nifẹsi:
- Se otitọ ni pe Kakanfo ki pẹ laye?
- Sé o leè kópa nínú ìdíje jíjẹ ata tútù ?
- Wo ọkùnrin kan tó fi N1.2m gbẹ́ ibojì rẹ̀ sílẹ̀ nígbà tó sì wà láàyè
- 'Colour Ghana Must Go' ló tú àṣírí Tọkọtayà náà níbi tí wọ́n kó ifún ọ̀rẹ́ ìyàwó tí wọ́n pa tà náà sí- Baale Leme
- Makinde buwọ́lu Sẹ́nẹ́tọ̀ Lekan Balogun gẹ́gẹ́ bí Olubadan tuntun
- ‘Isẹ́ tíátà pé mi láì mú nkàn míì mọ’