You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Awọn to bori, awọn to f'idirẹ'mi ninu Champions League
Tottenham ti pada s'oju opo aṣeyọri pẹ̀lu bi o ṣe ta ọ̀mọ̀ pẹ̀lu Juventus lẹ́yin ipinlẹ to o mẹ́hẹ lasiko ti idije Champions League bẹ̀rẹ̀.
Ikọ̀ Mauricio Pochettino lo kọ́kọ́ gba bọ́ọ̀lu sinu awọ̀n lẹ́ẹ̀meji laarin iṣẹ́jú mẹ́waa ti ifẹ̀sẹ̀wọnsẹ̀ naa bẹ̀rẹ̀ lẹyin ti Gonzalo Higuain gba pẹnariti wọle lati fi ṣe èrè fun fao to wa lati ọdọ Ben Davies nigba ti o ti Federico Bernardeschi ṣubu.
Oludari Manchester City, Pep Guardiola gboriyin fun Ilkay Gundogan fun bi o se fakọyọ lasiko ti ikọ Man City gbe igbesẹ akin nipele to wa saaju eyi to kangun si aṣekagba idije ife ẹ̀yẹ Champions League.
Man City gba isakoso nigba to ku ọgbọn iṣẹju ki ifẹ̀sẹ̀wọnsẹ̀ naa wa s'opin.
Awọn ifẹ̀sẹ̀wọnsẹ̀ ti yoo waye loni ni:
Real Madrid vs Paris Saint Germain
FC Porto vs Liverpool