Hassan Adesanya, Mr Success: Bọ̀ọ́lù ní mo fẹ́ gbá jẹun ṣùgbọ́n ẹ̀sẹ̀ mi kán ló sún mi dé ìdí àwàdà
Emi ti n ri ara mi bii 'Pastor' - Mr Success
Hassan Abayomi Adesanya ṣalaya ohun to bi orukọ 'Mr success'ti o n jẹ to fi rọpo orukọ 'Ọti oosa'to kọkọ n lo.
Bakan naa lo ṣorọ nipa irinajo aye rẹ ati ohun ti oju ri ko to de ibi to de lonii.
- Lẹ́yìn ò rẹyìn ìjọba àpapọ̀ tú àwọn ọmọ ìkọ̀ IPOB mẹ́ta sílẹ̀
- Kíló kàn? Wo ọ̀pọ̀ èrò tó ti ń wá wo Òkú Obabìnrin Elizabeth II ní Gbọ̀ngan Westminster
- Mi kìí mu ìgbó, sìgá, ọ̀tí rárá, ọmọ jẹ́jẹ́ ní mi- Ose Ose ọmọ Banke
- Èmi kò ni 'Problem' mo ní ọpọlọ tó pé ṣùgbọ́n...- Akẹ́kọ̀ọ́ LAUTECH
- Fídíò nípa Ìtàn ayé Ọbabìnrin Elizabeth Kejì tó jáde láyé
- 'Ọlọ́pàá yìnbọn pa àbúrò mi láti 2017, ọpẹ́lọpẹ́ ìwọ́de Endsars'
- Ẹ-̀wù gbèsè ni APC gbé wọ Nàìjíríà láti 2015, bí mo ṣe fẹ́ ṣe ètò ààbò àti ọrọ̀ ajé bí mo bá di Ààrẹ nìyí - Atiku
- Makinde pè fún ìkọ̀wéfipòsílẹ̀ Ayu gẹ́gẹ́ bíi alága ẹgbẹ́ òṣèlú PDP kí àláfíà lè jọba
Kini Mr Success tun sọ?
Hassan Adesanya menuba ibi ati idagbasoke rẹ lati agbegbe Itoko nilu abeokuta nipinle Ogun ni Iwo oorun Guusu Naijiria ni eyi to bi ede Egba to fi n se awada.
O sọ nipa bo ṣe wu oun lati maa gba bọọlu ko to di pe ẹsẹ oun kan ki o to tun ero rẹ pa.
Mr Success sọ iriri ati imisi to fi n se ọrọ iṣiti fun awọn eeyan rẹ.
O menuba ipa ti awọn ọrọ imọran yii ti ko ninu awọn eeyan.