Yollywood: Mistura Asunmo, Iya 2D: 1959 ni mo bẹ̀rẹ̀ eré ṣùgbọ́n ń kò ní ọkọ̀ ẹyọ kan di ìsìnyí
Àwa kò ni 'Pension' torí ọjọ́ ikú lọ́jọ́ ìsinmi lẹ́nu iṣẹ tiata- Iya Ika lomo ejo
Se ẹ ranti agba ọjẹ osere to kopa pataki ninu ere Ika lọmọ ejo ti Baba Wande ṣe lọpọlọpọ ọdun sẹyin?
BBC Yoruba ti wa iya to ṣe iya awọn ọmọge to n ko wọn ranṣẹ si awọn ọkunrin lati lọ fun ejo ni ounjẹ.
Mistura Asunmọ ti ọpọ n pe ni iya 2D salaye kikun nipa bo ṣe bẹrẹ ere itage ni ṣiṣe lati ọdun 1959.
- Yuroopu ni wọ́n sọ pé à ń lọ ṣùgbọ́n Morocco ni mo ti bá ara mi nínú iṣẹ́ aṣẹ́wó- Abosede
- Bí ikú ilé kò bá pani...ìkìlọ̀ rèé fún ẹ̀yin ọmọ Yorùbá tí ẹ n gbàbọ̀dè f'ájínigbé- Oba Francis Alao
- Irú ọmọ wo ní Yorùbá ń pè ní Olúgbódi?
- Owó oṣù 'Professor' ju ti 'Perm Sec' lọ nígbà tí mo bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní 1963- Emeritus Ayo Bamgbose
- A kò lè sọ pé Haram ní 'Oral Sex' nínú Islam ṣùgbọ́n Makrooh ni- Aafa Abdullateef
Kini Iya 2D tun sọ nipa irir re?
Mistura ṣalaye ipa ti ere n ko ninu igbe aye osere ati ipenija to n jade lati ara awon to n se ayederu kaseeti ti won n pe ni 'Piracy'
O sọ nipa ohun ti oju rẹ ri nipa bi awon eeyna se n tẹwọgba osere ati bi wọn tun ṣe n kọlu osere.
O menuba iṣoro aisi owo pa to ninu fiimu ti eeyan ba ṣe.
O rọ ijoba lati ba wọn wagbo dẹkun si ọrọ awon to n ji iṣẹ oṣere lo nigboro.