Èmi kan ń ṣiṣẹ́ olúkọ̀ ní abúlé tí wọ́n gbé mi ló fún Olọrun ni, mi ò ronú òyè rárá- Ajayi Olanrewaju
Omo ipinle Ekiti ni mi ṣùgbọ́n ipinlẹ̀ Ondo gbè mí nitori mo fi ọkan kan ṣe iṣẹ isinru ilu- Olanrewaju
Idi iṣẹ ẹni la ti n mọni lọlẹ. Ere n bẹ fun ọmọ to ba lapa iṣẹ ti ko ṣe ọlẹ.
Agunbanirọ ni Ajayi Olanrewaju to n sinlẹ Naijriria ni agbegbe Imade nipinlẹ Ondo ni guusu iwo oorun Naijiria.
Nigba ti awọn ara ilu ri bo ṣe n fi tókan tara ṣiṣẹ olukọ to n kọ awon ọmọ ile ẹkọ girama Imade
- Ìdí tí àwọn ìbejì mi, Twinz love ṣe ń rí mi mú fi ṣe “prank” wọn rèé – Ìyá Ìbejì
- -Mo ní àìsàn Lupus, n kò le bá ọkọ mi lòpọ̀ fún ọdún márùn-ún àkọ́kọ́ lẹ́yìn ìgbeyàwó-
- Àsìkò wo ló yẹ kí obìnrin bẹ̀rẹ̀ ìbálòpọ̀ padà lẹ́yìn ìbìmọ láìséwu?
- BBC tú àṣírí àwọn tó ń kó ọmọdé ṣòwò ẹrú
- -Mo ti bí ìbejì nígbà márùn ún ọ̀tọ̀tọ̀, àmọ́ mo ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ ni-
- Àlàyé rèé lóri nkán tó wà nìdí làásìgbò tó bẹ́ sílẹ̀ ní ìlú Igangan
Ajayi Olanrewaju tun salaye fun BBC yoruba bi inu awọn Obi oun se dun to nigba ti wọn gbọ pe wọn fẹ fi oye da oun agu8nbanirọ lọla ni ipinle Ondo.
Bakan naa lo tun gba awọn agunbaniro bii tire nimoran pe ki won gbe jẹ fun ori nitori pe Eledaa lo mọ ibi ti ori n gbe ẹsẹ re.