EndSARS rememberance: Ohun táwọn afẹhóúhàn bèrè fún ní Lekki lónìí rèé

Àkọlé fídíò, Wo ìyà tó jẹ Adedotun Clement níbi ìwọ́de EndSARS ní Lekki Toll Gate àtohun táwọn tó sọ̀rọ̀ ń bèrè fún

Ọrọ iranti ayajọ iṣẹlẹ iwọde EndSARS naa ti darapọ mọ owe Yoruba to ni ọdọọdun la n ri orogbo, ọdọọdun la n ri ọmọ obi ni atẹ.

Eyi jẹ bẹẹ toripe lọdun to kọja gaan ni iṣẹlẹ yii waye ni agbegbe Lekki ni eko amọ to pada di ranto dti gbogbo agbaye si mọ sii.

Ohun lo mu ki awọn ọdọ tun bọ sigboro lonii lati saami ọjọ naa.

Amọ oriṣiriṣi lo ṣẹlẹ nibẹ o. Fidio yii ṣafihan ara awọn nkan manigbagbe ti akọroyin BBC Yoruba foju gaani nibi iwọde naa.