Barry Jhay's latest news: Èmi náà rí fídíò tó fi síta tí ẹnu rẹ̀ ti ń ṣẹ̀jẹ̀ kò tó di pé ọ
Olaronke Balogun to jẹ ẹgbọn fun Barry Jhay ni awọn ṣi wa lori ọrọ yii torinaa iwọnba ni ẹbi le sọ nipa rẹ.
"Mi o si nibẹ ṣugbọn ọmọ to da a ni aburo mi, o ni iwa to daa, ko si ni ọwọ ninu iku naa".
- A ò lè kọ ẹbí olóògbé Kashy bí wọn ṣe máa hùwà torí ọmọ wọn papòda àmọ mo mọ̀ pé Barry Jhay... - Ẹbí Sikiru Ayinde Barrister
- 'Olóògbé Kashy ra ago olówó iyebíye N9m fún Barry Jhay ní ó ku ọ̀jọ́ díẹ̀ kó papòdà'
- Ṣé lóòtọ́ ni Alaafin Ọyọ ti fẹ́ olorì tuntun láti ẹ̀yà Igbo? Ẹ wo ǹkan tí a mọ̀ nípa rẹ̀
- Fásitì Ilorin ti akẹ́kọ̀ọ́ mọ́lé tórí ó fi "yẹrín etí" sí imú, ohun tí wọ́n sọ f'áráàlù rèé
Olaronke ni awọn gbọ wipe oloogbe Kashy ti ni awọn iṣoro kọọkan to n koju ṣaaju ọjọ iku rẹ.
Koko ọrọ to tẹnumọ ni wipe idile Barrister nigbagbọ ninu ọmọ tiwọn, awọn o lodi si ohun ti idile oloogbe Kashy n ṣe amọ sibẹ sibẹ awọ́n ni lati gbe igbesẹ toripe Barry Jhay ko jẹbi rara.
- Wàwúù!!! Lẹ́yìn ọmọ márun-ùn, wo bí ìyàwó àgbẹ̀ se tún bí ìbaàrùn-ún ní Ogbomoso láì ṣe iṣẹ́ abẹ
- Bí ilé ẹjọ́ bá pàṣẹ kí Krìstẹ́nì àti Mùsùlùmí máa pe Ọlọ́run ní Allah, kí lẹ ó ṣe?
- Mọ̀ síi nípa ìṣẹ̀lẹ̀ ilẹ̀ ríru tó mú ẹ̀mí 16,000 èèyàn lọ tó sì ba dukia $206b jẹ́
- Mo wádìí nínú Quaran, mo ka Hadith mo sì ríi pé gígun ẹṣin kò lòdì sí ẹ̀sìn Islam - Jemila
