India: Ẹ wo bí àwọn ènìyàn ṣe dóòlà èmí erin tó jálulẹ̀

Àkọlé fídíò, India: Ẹ wo bí àwọn ènìyàn ṣe dóòlà èmí erin tó jálulẹ̀

Ọpẹlọpẹ awọn oṣiṣẹ pajawiri ati awọn araalu Tamil, lorilẹede India ni wọn jade lati doola erin to ja si koto ni agbegbe naa.

Wakati mẹrinla ni wọn lo ko to di wi pe wọn lo ohun igbe nkan lati fi faayọ kuro ninu ihọ naa.

Ohun ti wọn kọkọ ṣe ni pe wọn gbọ omi to le ni mita mẹrindinlogun kuro ninu ihọ̀ naa, ki wọn to bẹrẹ si ni wa ọna lati yọ.

Lẹyin ọpọlọpọ igbiyanju ni wọn ri yoo ti o si dide lori ẹsẹ rẹ mejeeji.