Ifa Priest: ọdún mọ́kànlá ni mo fi ṣe iṣẹ́ agbejọ́rọ̀ kí n tó gbọ́ràn si Ifá lẹ́nu
Emi naa ko kọkọ gba pe Ifa ni mo ṣi maa jokoo ti- Oludari Ifadiwura Tempili
Iyanifa Popoọla Ella Agwu to fi ilu oyinbo ṣe ibujoko to n dari tẹmpili Ifadiwura ni ilu Ọba sọrọ ni kikun lori igbesi aye rẹ fun BBC.
O sọ nipa iṣẹ agbẹjọrọ to fi ọdun mọkanla ṣe ko to pada wa gbọran si Ifa lẹnu ko to maa ṣe iṣẹ Ifa dida.
- Kékeré ni mo ti nífẹ̀ẹ́ Òrìṣà - Ọmọ ilẹ̀ Brazil
- Wo àgbáríjọpọ̀ àwọn Arugbá Ọ̀ṣun Òṣogbo látìgbà tó ti bẹ̀rẹ̀
- Owó, ọmọ, àlááfíà àti àìkú á bá gbogbo wa gbé ni 2020- Oloye Ifaleke
- Ọba tèmi ò ba lórí ohun gbogbo!-Taiwo Oyebola Agbona
- Àwọn sẹ́nétọ̀ Nàìjíríà fa ìbínú yọ 'torí N2Miliọ̀nù owó àjẹmọ́nú Kérésì tí wọ́n fún wọn
Iyanifa Agwu sọrọ lori bi oun ṣe ba Ifa dida nile nitori pe Oluwo ni baba rẹ to bii nigba ti iya ẹ jẹ Iyanifa pẹlu
Ella mẹnuba irufẹ awọn eniyan orilẹ-ede bii Brazil, Jamaica, Trinidad, Tobago, Ukraine atawọn orilẹ-ede ilẹ Adulawọ mii.