Water Rescue: Inú ìyàwó dùn pé wọ́n rí òkú ọkọ rẹ̀ yọ nínú odò
"Inú mi dùn láti fún àwọn ẹbí làǹfànÍ ṣíṣe ẹ̀yẹ ìkẹhìn òkú wọn"
Aburo Keith ku nigba to n gbiyanju lati gba ẹni to ri ninu omi la. Eyi ni iriri manigbagbe rẹ to si tori rẹ pinu lati maa ṣe iṣẹ aanu naa lọ.
Eyi lo mu Keith ṣi ile iṣẹ to n luwẹẹ ni ilana ti igbalode lati le maa ṣa gbogbo akitiyan lati yọ ẹni to ba ko sinu omi.
Igba kuugba ti o ba ṣe aṣeyọri yiy oku jade ninu omi, inu awọn ẹbi oloku a maa dun pe o n fun awọn ni anfani lati le ṣe ẹyẹ ikẹyin fun eeyan wọn.
- Fáàbàdà! Peter Okoye lóun ò ṣèlérí N60m fún Tacha, Zlatan gbórin tuntun jáde
- Ariwo sọ, wọ́n fọwọ́ òsì júwe ilé fún Tacha lórí ètò àgbéléwò BBNaija
- Kàyééfì rèé! Kábíyèsì fẹnu ara rẹ̀ tú àṣírí àwọn Fulani Daran daran tó ń ṣọṣẹ́ nílùú rẹ̀
- Èèmọ̀ rèé! Àṣírí ilé tí wọ́n ti ń fipá bá àwọn ọmọdékùnrin lò tú síta
- Ta ni 'Mad Melon' ọ̀kan lára àwọn akọrin Danfo Driver tó d'olóògbé?