Ààrẹ Túnisia kú sẹyin odi lẹ́ni ọdun mẹtalélọ́gọ́rin

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ààrẹ Tunisia nígbà kan rí President Zine el-Abidine Ben Ali tí kú sí ẹ̀yin odi lẹ́ni ọdun mẹ́tàlélọ́gọ́rin.
Ben Ali tó dari orílẹ̀-ede náà fún ọdún mẹ́talélógun, sùgbọ̀n gbogbo ìlú mọ̀ọ́ si ẹni to mu ìlọsíwáju ba ètò ọ̀rọ̀ ajé orilẹ̀-èdè náà.
- Ìjà Toyin àti Lizzy kìí ṣe àkọ́kọ́, àwọn òṣèré t'ọ́rọ̀ ìjà kàn rí rèé
- Kò sí ìdí láti tọrọ àforíjì lọ́wọ́ Nàìjíríà - Alákòso Johannesburg
- Folashade Yemi-Esan, ohun tó yẹ kóo mọ̀ nípa adarí ẹ̀ka òṣìṣẹ́ ọba tuntun
- A ti kọwé sí ìjọba àpapò làti pe agbaṣèṣe odò Asa padà- Gomina Kwara
- Oògùn olóró cocaine ni Toyin Abraham fi ń sayé - Lizzy Anjorin
Sùgbọ́n ọ̀ps lo n náwọ àtako nítori ó n tako òṣèlú awa ara waàti ìwà àjẹbánu.
Ní ọdun 2011, wan le kuro nílu pèlú ìfẹ̀honu han, èyi lo si far rogbodiyan lorisirisi ni ààrin àwọn ẹya Arab.










