Kollington vs Barrister: Ọ̀rẹ́ ni èmí àti Barrister kó tó jáde láyé
Ọmọ ni Wasiu Ayinde Marshall jẹ́ si mi -Kollington.
Alhaji Ayinla Kollington to je agba oje olorin Fuji ni Naijiria gba BBC lalejo nile won fun iforowanilenuwo.
Baba kebe n kwara dahun ibeere nla to n fa ariyanjiyan lagboole Fuji lori eni to da ere Fuji sile.

Oríṣun àwòrán, OTHERS
O ni ere Fuji ti wa saaju ki oun ati Ayinde Barrister to bere orin kiko rara.
O ni oro apara lasan ni pe oun tabi Barrister ni awon jo da fuji sile.
- Ọkọ̀ òfurufú ọmọ ogun Nàìjíríà fi àdó olóró pa ọ̀pọ̀ èèyàn ní Zamfara– Aráàlú
- Tọkọtaya wọ “jẹsí” Messi àti Mbappe lọ́jọ́ ìgbéyàwó
- Ọkọ mi máa ń fún mi lóògùn orun lálaalẹ́ kó tó fipá bá ọmọ tó ń gbé lọ́dọ̀ mi lòpọ̀ - Ìyàwó Doctor Olaleye
- Orí Tẹlifísàn mà ni mo ti rí Sunday Igboho rí láyé mi, bí ìyà ṣe jẹ mi gbé láti Ibadan, dé Àtìmọ́lé DSS rèé - Ifasooto Dada
Baba Alatika be gbogbo olorin Fuji lati jebure ki won fowo wonu.
O fi Olorun ati Anobi Muhomo be gbogbo olorin fuji ti won je kikida musulumi pe ki won dupe ti won.
Aajo aje ni eebu ti emi ati oloogbe Ayinde Barrister fi n bu ara ninu ariyanjiyan wa ninu orin fuji.
Koda aw'on Baba nla wa ninu ise orin gan an korin bu ara won ki onikaluku le ta oja tire.
- Alábàárù ni mò ń ṣe lọ́jà Ketu àti Mile 12, kí ń tó bẹ̀rẹ̀ Fuji - Atawẹ́wẹ́
- Àìle è ka kéú ló sọ mí di Krìstíẹ̀nì - Adewale Ayuba
- Barrister ló sọ mí di èèyàn ńlá - Ayinla Kollington
- Ọ̀pọ̀ ló ṣì n ṣelédè lẹ́yìn Barrywonder!
- Àwọn ọmọ Nàìjíríà tó lọ sókè òkun ṣì ń padà bọ̀ wá sílé, àwọn òyìnbó gan an máa wá - Olórin Ayewa
Kollington ni ko le se ki ija ma wa laarin awon eniyan laye.
O gba imoran pe ti ija ba ti de ki onikaluku pari e ni alaafia fi le joba ni ile aye.