Ọ̀pọ̀ ìgbà ni a maa n ri awọn agbabọọlu ti a nifẹ si ṣugbọn ti wọn yoo wa ninu awọn ẹgbẹ agbabọọlu oriṣiriṣi.
Ti ẹ ba ni aanfani lati ko awọn ọmọ ẹgbẹ agbabọọlu ti yin jọ, ta ni yoo wa nibe?
Eyi ni anfani lati yan awọn ti ẹ fẹ sinu ẹgbẹ agbabọọlu aayo yin yii.
Nipa irinṣe ajumọlo wa,yan ikọ ti o wu ọ lọkan ninu awọn ti a ṣe aṣayan wọn ki o ṣi ṣe alabapin rẹ pẹlu awọn ọrẹ rẹ.