ICPC ti ní adarí tuntun, Ọ̀jọ̀gbọ́n Owasanoye ló ń jẹ́

Prof. Bolaji Owasanoye

Oríṣun àwòrán, ICIR

Ile Igbimọ Aṣofin Agba ti buwọ lu iyansipo Ọjọgbọn Bolaji Owasanoye gẹgẹ bii adari tuntun fun ajọ ICPC.

Awọn to jẹ ọmọ igbimọ ti yoo dari ICPC pẹlu ọjọgbọn naa ni Grace Chinda (Ipinlẹ Delta) Okolo Titus (Ipinlẹ Enugu), Obiora Igwedebia (Ipinlẹ Anambra), Olubukola Balogun (Ipinlẹ Lagos ), Adajọ Adamu Bello (Ipinlẹ Katsina), Hannatu Muhammed (Ipinlẹ Jigawa), Abdullahi Saidu (Ipinlẹ Niger) ati Yahaya Dauda (Ipinlẹ Nasarawa).

Oun ni yoo rọpo Ojọgbọn Musa Abubakar to ti n ṣe fidi hẹ ni ajọ naa tẹlẹ.

Àwọn ìròyìn mìíràn tí ẹ lè nífẹ̀ẹ́ sí: