Kinni wọn n pè ni oṣupa déjé ní kíkún?

Àkọlé fídíò, Kinni wọn n pè ni oṣupa déjé ní kíkún?

Laarin ogunjọ si ọjọ kọkanlelogun, oṣu kinni, 2019 laagomẹta aabọ ni Naijiria ló maa ṣẹle.

Oṣupa to dẹjẹ ṣẹlẹ fun igba akọkọ nigba aye awọn oludasilẹ Amẹrika.

Oṣupa maa n dẹjẹ nigba ti oṣupa ba kọja lára òjìjí ayé.

Laarin ogunjọ si ọjọ kọkanlelogun, oṣu kinni, 2019 laago mẹta aabọ ni Naijiria ló maa waye.

NASA Scientific Visualisation Studio ni wọn ṣagbekalẹ iṣe iwadii yii pẹlu The Old Farmer's Alamanac.

Iwadii wọn fihan pé Opọlọpọ aawọ oòrùn lo yi ayé po, ṣugbọn aawọ pupa maa n gun pupọ, o maa n kọja lara oṣupa to fi maa tàn nigba ti iṣẹlẹ yii ba ṣẹlẹ lagbaye.