Esusu fi bó ṣe tó gbangba sùn lọ́yẹ̀ tó hàn lórí ètò Ṣó o láyà

Àkọlé fídíò, Ṣó o láyà?
Esusu fi bó ṣe tó gbangba sùn lọ́yẹ̀ tó hàn lórí ètò Ṣó o láyà

Òṣèré tíátà nnì, Aliu Gafar tí ọ̀pọ̀ mọ̀ sí Esusu fún ipa tó kó nínú eré fíìmù Seven Doors tí Femi Adebayo gbé jáde ti fi bó ṣe dáńtọ́ nínú èdè Yorùbá sí hàn lórí ètò Ṣó o láyà.

Esusu ní ọmọ Yorùbá tó gbójú gbónu ni òun, tó sì fi èyí hàn lórí ètò náà.

Ẹ wo fídíò òkè yìí láti rí bó ṣe nímọ̀ nípa èdè, àṣà àti ìṣe Yorùbá tó.

Aliu Gafar