Mọ̀ nípa èròjà aládùn tí wọ́n fi ń rọ́pò ṣúgà nínú oúnjẹ́, tó ń ṣe àkóbá fún àgọ̀ ara
Mọ̀ nípa èròjà aládùn tí wọ́n fi ń rọ́pò ṣúgà nínú oúnjẹ́, tó ń ṣe àkóbá fún àgọ̀ ara
BBC News Yoruba ṣe akojọ imọ ijinlẹ lori ohun aladun ti awọn oloyinbo n pe ni sweetener, eyi ti wọn n fi rọpo suga ninu ounjẹ lasiko yii.
Awọn akọsẹmosẹ imọ ijinlẹ sayẹnsi ni awọn ileeṣẹ kan n lo awọn aladun sweetener ti wọn n pe ni Sorbitol ninu ohun ifọyin, chewing gun, ohun ẹlẹrindodo ati awọn nnkan mii.
Iwadii ti fi han pe Sorbitol n fa aisan ẹdọ lago ara eeyan, iwadii tun ni ẹnikan laarin eeyan marun un lo ṣeeṣe pe ko ti ni aisan yii.
Iwadii tun fi di rẹ mulẹ pe ọpọ eeyan ni ko mọ pe wọn ni aisan yii nitori wọn ko lọ ṣe ayewo ara wọn.
Ẹkunrere alaye wa ninu fidio ti a gbe soke.




