Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ṣe lootọọ ni Baba Ijesha ti gba itusilẹ kuro lọgba ẹwọn?
Bẹẹ la a bi ni o, emi naa ri iroyin ọhun lori ayelujara
Idi ree ti BBC Yoruba fi kan si agbẹjọro Baba Ijesha
Alaye ohun to sọ wa lori ikanni BBC.Com/Yoruba
'''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Donald Trump yari lori iroyin to sọ pe ikọlu Amerika si ibudo iko nnkan ija oloro si Iran ko tu irun kankan
Ajọ ọtẹlẹmuyẹ DIA to n maa n ṣe iwadii fun ileeṣẹ ọmogun Amẹrika lo sọ pe
kii ṣe gbogbo ibudo iko nnkan ija oloro Iran ni Amẹrika bajẹ lopin ọsẹ to kọja.
Amọ, Trump yari, o ni ọrọ ko ri bẹẹ rara
'''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
N jẹ o ranti iroyin ti BBC Yoruba gbe lana lori awọn akẹkọọ fasiti ipinlẹ Kwara, KWASU to ke gbajare lori bawọn agbebọn ṣe n ja won lole?
Bẹẹ ni, ki ni tuntun lori ọrọ naa?
Awọn alaṣẹ ile ẹkọ naa ti gbe awọn igbesẹ kan lati daabo bawọn akẹkọọ bayii
Fun ẹkunrẹrẹ iroyin yii ….
















