Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
Njẹ o mọ pe ijọba ana nipinlẹ Osun ya ogun miliọnu dọla lati kọ ile iwosan alabọde amọ wọn ko kọ ile iwosan naa
Irọ ni o! Bawọ niwọ ṣe mọ?
Gomina ipinlẹ ọhun, Ademola Adeleke lo sọ bẹẹ fun BBC Yoruba ninu ifọrọwerọ kan
Ẹhn.. Ẹhn..
Adeleke ni ijọba oun ko fi ọrọ araalu ṣere bii ijọba ana
Hmmmm....
Kan soju opo wa fun ẹkunrẹrẹ
Niluu Eko
Agunbanirọ to fi ohun ranṣẹ si ijọba Tinubu lori ipo ti ọrọ aje Naijiira wa, Ushie Uguamaye
Ti ke gbajare sita pe ajọ NYSC n dunkoko mọ oun
Ẹwẹ, igbakeji Aarẹ Naijiria tẹlẹ, Atiku Abubabar atawọn ajafẹtọọ ọmọniyan kan ti ni ohun ti ọdọbinrin naa sọ ko buru, ati pe ki wọn fi lọrun silẹ
Iye eeyan to ku lẹyin ina to ṣẹyọ nile ijo kan ni North Mcedonia ti pe mọkandinlọgọta bayii
Nnkan bii aago mẹta oru ni ina naa dede ṣẹyọ nile ijo ọhun lasiko ti awọn eeyan to wa nibẹ n ṣe faaji lọwọ
O le lọgọrun eeyan to farapa yanayana nibẹ













