Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
Abisola Kola-Daisi, Ọmọ gomina ipinlẹ Oyo tẹlẹ, Abiola Ajimobi, ti jade laye.
Iku doro.
Owurọ Ọjọbọ ni iroyin ni iroyin sọ pe Abisola ku lorilẹ-ede United Kingdom lẹni ọdun mẹrinlelogoji
mmmmmmmmmmmmmmmmmmmmmmmmmmmmm
Gomina Seyi Makinde ti yi ọrọ pada lori ofin Sharia l'Oyo
Ṣaaju lo ti loun yoo gbe igbimọ naa lọ si kootu.
Bayii nko?
Makinde sọ pe awọn to ba fẹ, le ko ẹjọ lọ siwaju igbimọ naa lati ba wọn dajọ, yala musulumi tabi ẹlẹsin miran
O ni eyi yoo din ẹjọ tawọn adajọ n gbọ ku
Amọṣa, Ọjọgbọn Isiaq Akintola, Oludasile ajọ MURIC to n ja fun ẹtọ Islam lawọn ko fẹ ki Kristẹni lo Sharia.
Akintola sọ pe Musulumi nikan lofin naa wa fun
Ki lo de ti MURIC sọ eyi lẹyin to ti n pe fun Sharia tipẹ
Ka a ni BBC.COM/YORUBA
,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,
Orilẹede Niger ti bura fun Abdourahamane Tchiani gẹgẹ bi aarẹ ologun
Ọgagun Tchiani ni olori awọn ṣọja to gbajọba lọwọ aarẹ alagbada, Mohamed Bazoum lọdun 2023.
Ọdun marun ni yoo fi lo ipo, lẹyin to tu awọn ẹgbẹ oṣelu ka.

