Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Àkójọpọ̀ ìròyìn káàkiri Nàìjíríà
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

E! e! oluwa rẹ lowo lakoto banki, a o ri na

Ki lo ṣe ẹ ti o n dasọ bayii?

Ṣe bi ṣege bansa ti ile ifowopamọ mi yii n foju mi ri lori owo mi ni

Ṣe iwọ ko mọ ajọ to n ri sọrọ awọn onibaara ti n da si ọrọ naa

FCCPC ni awọn ti ranṣẹ pe awọn ileeṣẹ to n da awọn onibaara wọn lagara

Ajọ to n ri si iwọle-wọde ni Naijiria, Nigeria Immigration ti sọrọ lori awuyewuye to gba ori ayelujara

Ṣe eyi ti wọn fi fẹsun kan wọn pe iyawo ile nilo lati fi passport ọkọ rẹ silẹ ko to le ṣe tirẹ?

Bẹẹ ni o, amọ Immigration ni bẹẹ kọ lọrọ ri

Ẹnu ti n kun Aarẹ Joe Biden tilẹ Amẹrika

Lẹyin to kede wi pe oun ti dariji ọmọ oun, Hunter Biden

lori ẹsun to nii ṣe pẹlu lilo ibọn lọna ti ko tọ ati owo ori, eyi ti wọn fi kan an.

Biden kede idariji naa lọjọ Aiku bo tilẹ jẹ pe o ti kọkọ sọ pe oun ko nilo ipo oun lati ṣaforiji fun Hunter

Fun ẹkunrẹrẹ awọn iroyin yii

Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́