Golí ikọ̀ Eagles Nàìjíríà, Christian Obi jáde láyé nínú ìjàmbá ọkọ́

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 3

Aṣọle fun ikọ agbabọọlu Super Eagles Naijiria nigba kan ri, Christian Obi ti jade kaye ninu iṣẹlẹ ijamba ọkọ kan to waye ni Ọjọ Ẹtilopopona to lọ si Abakaliki ni ipinlẹ Ebonyi.

Ikọ ẹgbẹ agbabọọlu Heartland FC lo n ko sodi lọ si ibi idije TICO/SELECT ti wọn fẹ fi igbaradi fun saa liigi tuntun.

Bọọsi kan ninu mẹta ti ẹgbẹ agbabọọlu naa n gbe rin irinajo naa lo kọlu ọkọ nla kan to duro loju popo lasiko to fi n gbimọran ati ya fun ọkọ kan to n bọ niwaju wọn.

Ni nnkan bi agogo nẹrin irọlẹ ni ìṣẹlẹ naa ṣẹlẹ.

Ikọlu naa ba Christian Obi to jẹ akọnimọgba ikọ Heartland lojiji to si mu ko kọkọ daku lọ pẹlu ọgbẹ diẹ lẹsẹ ọtun rẹ.

Wọn ko Akọnimọọgba naa at’awọn agbabọọlu to fi ara ṣeṣe lọ si ile iwosan kan ni ilu Okwelle ni ipinlẹ Imo nibi to ti pada dagbere f’aye.

Ajọ akoso ere bọọlu ni Naijiria, NFF daro Christian Obi

Ajọ NFF ti ṣe apejuwe iku Christian Obi, akọnimọọgba Heartland FC to jade laye naa gẹgẹ bi eyi to bani ninu jẹ pupọ.

Aarẹ ajọ naa, Ibrahim Gusau ṣalaye ninu atẹjade kan pe ajalu nla ni iṣẹkenaa jẹ fun ajọ naa ati gbogbo awọn ololufẹ bọọlu lorilẹede Naijiria.

Ohun ti a mọ nipa Christian Obi

Christian Obi fi igba kan ri jẹ aṣọle fun ikọ agbabọọlu ọdọ ti ọjọ ori wọn ko ju ogun ọdun lọ ni Naijiria, iyẹn Nigeria U20 to di Flying Eagles bayii.

Ikọ naa lo gba ami ẹyẹ vaba kẹyin ti wọn ṣe ipo jẹta nibi idije ifẹ ẹyẹ agbaye fun awọn ọdọ, FIFA U20 World cup, ti ajọ bọọlu lagbaye, FIFA ṣe lọdun 1985 lorilẹede Soviet Union nigba naa.

Bakan naa lo wa lara ilọ agbabọọ Naijiria lọkunrin to kopa ni idije Olympiki l’ọdun 1988 ni Seol lorilẹede Japan.

Akọnimọọgba ẹgbẹ agbabọọlu Heartland FC ni ki ọlọjọ to de ni ọjọ Ẹti, ọjọ kẹtalelogun oṣu kẹjọ ọdun 2024