Wọ́n rí alágbàtọ́ fún ìkókó tó jàjàbóͅ lọ́wọ́ ikú lásìkò ìsͅèͅlèͅ ilèͅ ríri ní Turkey

Oríṣun àwòrán, Reuters
Oͅmoͅ jojolo ti woͅn bi lasiko ti isͅeͅleͅ ileͅ riri da ile woͅn wo lorileͅede Turkey ti ri alagbatoͅ
Oͅmoͅ jojolo nikan naa ni ko ku ninu isͅeͅleͅ ileͅ riri naa ni Turkey, leͅyin ti iya reͅ ku, baba reͅ awoͅn eͅgboͅn reͅ meͅrin to fi moͅ awoͅn moͅleͅbi reͅ.
Eͅgbeͅgbeͅrun awoͅn eniyan lo ti fi ifeͅ woͅn han si oͅmoͅ jojolo naa, ti woͅn si feͅ ko jeͅ oͅmoͅ woͅn leͅyin ti woͅn d doola eͅmi oͅmoͅ naa.
‘’Ibatan iya reͅ lo gba oͅmoͅ jojolo naa lati toͅju’’
Amoͅ nibayii, awoͅn ibatan iya reͅ ni woͅn ti gba oͅmoͅ naa lati toͅju reͅ geͅgeͅ bi ti woͅn.
Awoͅn dokita ni leͅyin ayeͅwo eͅjeͅ, ti woͅn ri pe moͅleͅbi reͅ ni, ni woͅn se fi oͅmoͅ naa fun woͅn lati toͅju.
Bakan naa ni dokita ni oͅmoͅ naa wa ni alaafia.
Ibatan reͅ naa to gba lati toͅju reͅ ni o ti di oͅmoͅ wa lati oni loͅ, ti ko si ni moͅ iyatoͅ laarin reͅ ati awoͅn oͅmoͅ to ku
Woͅn si ti soͅ orukoͅ oͅmoͅ naa ni Afraa, eyi to jeͅ orukoͅ ti iya reͅ n jeͅ nigba to wa laye.
Bi woͅn se doola eͅmi oͅmoͅ jojolo naa…
Lasiko ti woͅn doola eͅmi reͅ ni woͅn soͅ ni Aya, eleyii to tumoͅ si ‘’isͅeͅleͅ iyaleͅnu.’’ Ni ede Arabu.
Lori ayelujara ni fidio bi woͅn se doola eͅmi oͅmoͅ naa gbaye kan leͅyin isͅeͅleͅ ileͅ riri naa.
FIdio naa sͅafihan rakunrin kan to n saloͅ peͅlu oͅmoͅ tuntun jojolo , ti eruku sib o oͅmoͅ naa ni oͅwoͅ reͅ.
Oͅmoͅ naa lo w ani abeͅ ile to ti wo naa fun wakati meͅwaa, ti dokita si ni irisi reͅ ko dara nigba ti woͅn gbe de ile iwosan. Nise ni gbogbo ara reͅ kun fun egbo.
Moͅleͅbi reͅ ni ko peͅ ti ile naa dawo , ti iya reͅ beͅreͅ si ni roͅbi, amoͅ to bi oͅmoͅ naa ki o to ku.












