'Ayé ò níì padà já a yín sí ìhòhò lọ́dún tuntun'
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1
Bi ọdun 2026 ṣe n bẹrẹ yii lọ, Woli Israel Ogundipe , to jẹ oluṣọ agutan ninu ijọ CCC Genesis Global, gba adura fun awọn ọmọ Naijiria bi wọn ṣe n wọ ọdun tuntun lọ.
Ninu adura ọdun to ṣe pẹlu BBC Yoruba, Woli Ogundipe ti gbogbo eeyan tun mọ si Genesis gba adura pe ọdun ayọ, ọdun idunnu ni ọdun tuntun yoo jẹ.
O ni "ẹ ti jiya lori ọmọ, ẹ o ni pada jiya lọwọ ọmọ".











