Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Ko ṣee ma gbọọ
Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Iwadii BBC ma ti ṣafihan ibudo ayederu oogun kan ni India.

Nise ni wọn n ko oogun to le fa wahala sagọ ara naa wa silẹ Africa

Koda, o ti wa ni Naijiria pẹlu

Haa, bawo waa ni mo ṣe fẹẹ da a mọ ki n ma lugbadi

Kan si BBC. COM/ YORUBA

...........................................................................................................

Fún àǹfàní Nàìjíríà la ṣe fagilé ìbò June 12

Olori Naijiria lasiko ologun, Ibrahim Babangida, lo ṣalaye bẹẹ.

Ninu iwe itan aye rẹ to pe ni Journey in Service ni IBB ti jẹwọ pe Oloogbe MKO Abiola lo bori ibo aarẹ June 12 ọdun 1993.

Iyẹn lẹyin ọdun mejilelọgbọn abi

O ni boun ṣe fagile ibo naa fa ijọba Demokresi sẹyin fun Naijiria.

Ati ki tun ni?

<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<

Njẹ o tiẹ mọ ohun toju Portable ri ni kootu ki wọn too gba oniduro rẹ?

Emi o mọ o, amọ mo gbọ pe niṣe lo kunlẹ to n rawọ ẹbẹ nita kootu.

Aago mẹrin ni kootu n tilẹkun, oniduro Portable ko de tasiko fi to.

Bawo lọmọ Olalomi ṣe wa ṣe e

Kan si BBC.COM/YORUBA