Africa Eye: Coronavirus di adákẹ́jà ní Somalia, ikú ọ̀wọ́ọ̀wọ́ ń peléke si
Iwadii BBC Africa Eye balẹ silu Mogadishu, lorilẹede Somalia, nibiti iku ti di meji eepinni lai si iwadi nipa iru iku to n pa wọn.
BBC sawari rẹ pe laarin osu mẹrin pere, eeyan to le ni ẹgbẹrun meji lo ti ku iku aimọdi bi o tilẹ jẹ pe akọsilẹ ijọba ni eeyan ọgọrun ni Coronavirus pa.
Bi awọn eeyan si se n ku iku ọwọọwọ yii, sibẹ awọn araalu ko takete sira wọn, ti wsn si ni ibẹru ebi ga ju ti Coronavirus lọ.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Ikú Barakat Bello ní Akinyele gbé aláàánú pàdé ẹ́bí rẹ̀
- A ṣe ọdún Ọ̀ṣun lásìkò yìí láti kó Coronavirus lọ ni - Ooni ṣàlàyé
- Wo àwọn nǹkan tí o kò mọ̀ nípa 'Church of Satan'
- Àwọn afurasí ajínigbé tó tan oníṣòwò jáde ní ṣọ́ọ́sì wọ gàù Ọlọpaa
- Eré ìtàgé lórí ayélujára, àbíkẹ́yìn faraya pé iṣẹ́ ilé ń pá òun lórí, ó gbé òfin kalẹ̀ fún ẹbí
- Boko Haram 601 parí iléẹ̀kọ́, ìjọba yóò san ₦20,000 lóṣù fún ẹnì ìkọ̀ọ̀kan
- Aráàlú faraya torí èèyàn 63 tó dèrò ọ̀run ní Gúúṣù Kàdúná láàrin ọ̀sẹ̀ kan
Dokita meji, ibusun ogun laisi ẹrọ Fẹntilatọ, ni wọn fi n tọju eeyan miliọ̀nu mẹrindinlogun to wa lorilẹede Somalia.
Sugbọn iwadii BBC Africa Eye fihan pe arun Coronavirus jẹ ọkan lara iku to n pa awsn eeyan ni Somalia.