Àkọsílẹ̀ nípa okoòwò láàrin ilẹ̀ Áfíríkà àti UK

Oríṣun àwòrán, @BashirAhmaad
Lẹyin ti ilẹ UK kuro ninu ajọ Europe tan, ilẹ UK fẹ nu ibugbooro ba eto idokowo rẹ pẹlu awọn orilẹede nilẹ Afirika. Sugbọn iru idiyele wo ni eto okoowo ti wọn n se?
Se ilẹ Gẹẹsi si jẹ agbegbe to gbooro bi ju ajọ Yuroopu lọ, fun awọn orilẹede nilẹ adulawọ lati ko eroja wọn lọ?
Ẹ dan imọ yin wo pẹlu ere ọwọ yii, nipa sise afiwe awọn eroja tawọn orilẹede adulawọ to n ko ja lọ si ilẹ UK, pẹlu orilẹede to n ko awọn ọja naa lọ.











