You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Pásítọ̀: Jésù kò ní gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tó bà wá láyé
Oníwàásù orí amóunmáwòrán kan lorílè-èdè Amẹrika, ti ke gbajare sí àwọn ọmọlẹyìn rẹ pé kí wọn ra bàálù fún òun.
Ọrọ náà ko ba ma di awuyewuy,e bi kíì ṣe pé bàálù kẹrin lo n beere fún.
Jesse Duplantis ní, Ọlọrun sọ fún òun pé kí òun ra bàálù ayọkẹlẹ Falcon 7X, ti ìyè owó rẹ̀ jẹ́ millionu mẹrinlelaadọta dọla.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
Bákannáà ló sọ pé, bàálù náà se pàtàkì nítorí Jesu ko ni gùn Kẹtẹkẹtẹ ka lo si wà láyé.
Ọrọ náà ti mú iriwisi wa láti ọdọ àwọn èèyàn, tí àwọn kan sì n ka ẹsẹ bíbélì tó pé àkíyèsí sí àwon woli èké.
N sẹ ní Jesse Duplantis ya foto lẹgbẹ awọn bàálù to ti ra tẹlé.
Ọdún méjìlá sẹyìn ni mo rà awọn bàálù ti tẹlẹ.""owó ríbi ríbi sí ni mo n san láti fi èpo sínú wọn"