You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Èrò àwọn ènìyàn lórí ẹ̀rọ àyélujára nípa ìdámẹ́wàá sísan
Laipẹ́ yii, olusọ̀aguntan ijọ RCCG, pasitor Adeboye sọ ni gbangba fun awọn ọmọ ijọ rẹ̀ wipe, ẹni ti ko ba san idamẹwa ko ni lọ si ọ̀run.
Ẹ o ranti wipe, ọrọ ti nja rain rain tẹ́lẹ̀ lori pe Daddy Freeze fesi si ọ̀rọ̀ pasitọ̀ Adeboye lori sisan idamẹ́wa leyii ti Freeze fesi pe idamẹ́wo ko pọn dandan.
Latari eyi lori ẹ̀rọ ayelujara, awọn eniyan tun fesi lori eyi to sẹ̀ jẹ jade latẹnu pasitọ Adeboye.