You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Daddy Freeze s'alaye n to faa ti oun fi n tako idamẹwa
O mu awọn eri to gb'ọkan le to fi n tako sisan idamẹwa naa jade ninu Bibeli nigba ifọrọwanilẹnuwo kan pẹlu BBC.