Eid Mubarak: Àràmọ̀ǹdà àwòràn ìkíni ọdún Eid il Fitr òṣèré tíátà Yorùbá àti gbajúmọ̀ míràn rèé

Jakejado Naijriia lawọn musulumi ti n ṣe ajọdun Eid il Fitr. Ko yọ awọn elere tiata ati gbajumọ mii silẹ.

Aworan Cute Abiola

Oríṣun àwòrán, Instagram/thecuteabiola

Àkọlé àwòrán, Akramaka llah! Ọmọ weri wenu taara ni Cute Abiola.
Aworan Mustpha Solagbade ni Umrah

Oríṣun àwòrán, Instagram/mustiphasholagbade

Àkọlé àwòrán, Lati ilu Makkah ni Mustapha Sholagbade ti fi eleyi ranṣẹ sawọn musulumi pe wọn ku ọdun
Aworan ọga Bello ati ọkan ninu awọn ọmọ rẹ

Oríṣun àwòrán, Instagram/adebayo.salami

Àkọlé àwòrán, Ninu ki aworan yi wa lati ilu Alimi tabi ko si jẹ pe ni Ikorodu ni Oga Bello ti ki irun Yidi.Ki lẹyin ro?
Aworan Mide Martins ati Afeez Owo

Oríṣun àwòrán, Instagram/mydemartins/

Àkọlé àwòrán, Eleyi lawọn to gbafẹ n pe ni Sai Baba ati Sai Mama!
Aworan Adedimeji Lateef ati Mo Bimpe iyawo rẹ

Oríṣun àwòrán, Instagram/mo_bimpe/

Àkọlé àwòrán, Idile Adedimeji Lateef naa n ki yin pe Barka da Sallah
Aworan Queen Salawa Abeni

Oríṣun àwòrán, Instagram/officialsalawaabeni

Àkọlé àwòrán, Ijiwumi, Salawa yi n kọrin tuntun...Lọjọ Ọdun Mama ni ka ki yin pe Barka da Sallah
Aworan Mercy Aigbe

Oríṣun àwòrán, instagram.com/realmercyaigbe/

Àkọlé àwòrán, Iyawo Alhaji naa tun ree
Aworan Mercy Aigbe

Oríṣun àwòrán, Instagram/realmercyaigbe

Àkọlé àwòrán, ''Iyawo Alhaji'' ni apejuwe ti Mercy Aigbe fi juwe aworan yi.Alhaji nkọ?
Jude Ighalo ati awọn ọmọ rẹ

Oríṣun àwòrán, Instagram/ighalojude

Àkọlé àwòrán, Lati orileede Saudi naa leleyi ti wa. Jalabia Jude Ighalo ati awọn ọmọ rẹ yi n dawa lọrun!