International Nurses Day 2021: Wo ìpèníjà àti àǹfàní inú iṣẹ́ nọ́ọ̀sì- Adetokunbo Shaba
Bi ayajọ awọn nọọsi ṣe n lọ lagbaaye, Ọgbẹni Adetokunbo Shaba ti sọ pe gbogbo eeyan kọ lo le ṣe iṣẹ nọọsi.
Shaba to jẹ agba nọọsi ti lo ogoji ọdun lẹnu iṣẹ nọọsi.
O ni ati obinrin ati ọkunrin lo n ṣiṣẹ nọọsi nitori gbogbo eeyan ni aisan maa n ṣe.
- Wo bí ìwọ́de Yomi Fabiyi nítorí ọ̀rọ̀ Baba Ijẹsha to wa ni àhámọ̀ ọlapàá ṣe n lọ nílùú Eko
- Kàyèéfì! Wo ìdí tí àlùfáà ìjọ Aguda fi ń kó ère ìṣẹ̀nbáyé pamọ́?
- Ẹni tó bá ní láàkàyè, a mọ ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn, àwà ti kọ lẹ́tà, èsì t'Ọ́lọ́pàá sì fún wa rèé - Yomi Fabiyi
- Ǹkan dé o! Àwọn jàndùkú tún yìnbọn pa ọlọ́pàá méje lẹ́nu iṣẹ́, wọ́n dáná sun ọkọ̀ wọn
- Mo gbé ìgbésẹ̀ láti ṣẹ́ oyún ọmọ mi tuntun, ọkọ mi nàá sì faramọ́ nítorí pé...
- Ẹ tú Baba Ijesha sílẹ̀ pẹ̀lú Béèlì, ẹ má ṣi agbára òfin lò bí bẹ́ẹ̀ kọ́
- Àwọn olólùfẹ̀ Toyin Abraham ati Liz Anjorin ti gbé ọ̀rọ̀ wọn rù sórí, ẹ wo òjò òkò ọ̀rọ̀
Ọgbẹni Shaba sọ pe ijọba ko tii gbiyanju to fawọn nọọsi ki ọkan wọn le balẹ lẹnu iṣẹ.
O ṣalaye pe ijọba ni lati ṣeto to mọyan lori nipa owo oṣu awọn nọọsi, ohun elo iṣẹ, omi ati ina ati bẹẹ bẹẹ lọ.
Ọgbẹni Shaba sọ pe nọọsi kan lo yẹ ko wa fun eeyan ni Naijiria gẹgẹ bi o ti ri kaakiri agbaye.