US Vice President: Ẹ wo ìtàn obìnrin àkọ́kọ́ tí yóò jẹ igbákejì Ààrẹ ilẹ́ Amẹrika!
Sẹnetọ Kamala Harris ti ni bio tilẹ jẹpe oun ni obinrin akọkọ ti yoo dipo igbakeji aarẹ mu lorilẹede Amẹrika, oun gbagbọ wi pe ọpọlọpọ eniyasn ni yoo jẹ lẹyin oun.
Kamala Harris ni awọn arinrinajo wa si orilẹ-ede Amerika lati orilẹede India ati Jamica.
Ki o to di igbakeji aarẹ, oun ni olootu eto idajọ ni ipinlẹ California.
- Joe Biden Innauguration, Jill Biden: Tani ìyàwó Joe Biden tí yóò jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ nílẹ̀ Amẹrika?
- Wo àwọn ààrẹ Amẹ́ríkà mẹ́rin tí wọn rọ̀ lóyè àti ẹ̀ṣẹ̀ wọn
- Ilé aṣòfin Amẹ́ríkà yọ ààrẹ Donald Trump nípò fún ìgbà kejì
- Taa ni ọmọbìnrin Naijiria ẹni ọdún 26 tí Joe Biden yàn sípò olùbádámọ̀ràn lórí Covid-19 ní America?
- Joe Biden náà ti gba abẹ́rẹ́ àjẹsara Covid-19
Ẹkunrẹrẹ itan aye rẹ wa ninu fidio yii...