You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
EFCC: Ìwádìí lórí ẹ̀sùn ìwà jẹgúdújẹrá tí wọ́n fi kan Babatunde Fowler tó jẹ́ àdàrí iléeṣẹ́ FIRS tẹ́lẹ̀
Ileeṣẹ to n gbọ ẹsun iwa ibajẹ, EFCC ti bẹrẹ si ni fi ọrọ wa Ọga Ajọ to n risi owo ori labẹle lorilẹede Naijiria, Babatunde Fowler lẹnu wo.
Agbẹnusọ fun Ajọ EFCC, Wilson Uwujaren lo fi idi ọrọ naa mulẹ pe Fowler wa ni ileeṣẹ wọn lọwọlọwọ nibi ti wọn ti n fi ọrọ wa lẹnu wo.
Ajọ EFCC fi iwe pe arakunrin Fowler to tun jẹ adari ajọ to n risi ọrọ owo ori labẹle nipinlẹ Eko, ti oun naa si jẹ ipe wọn ni Ọjọ Aje.
Amọ, Ajọ EFCC naa ko sọ iru iwadii ti wọn n ṣe, ti wọn fi fi iwe pe e.
- Ta ni Wolii Olapade Agoro tó re ibi àgbà ń rè tí ayé ń pariwo rẹ̀ yìí?
- Ìbẹ̀rù-bojo gbalẹ̀ ní Oyigbo lẹ́yìn tí ọlọ́páà mẹ́ta àti sọ́jà kú nínú rògbòdìyàn EndSARS
- Banki Nàìjíríà, CBN ṣàlàyé nípa àwọn tó máa rí gbà nínú owó ìrànwọ́ N75b tíjọba gbé kalẹ̀
- Ta ni Wolii Olapade Agoro tó re ibi àgbà ń rè tí ayé ń pariwo rẹ̀ yìí?