Eld Kabir in Nigeria: Mùṣùlùmí àti Kristiẹni sọ̀rọ̀ nípa àdun oúnjẹ́ àti ẹran ọdún Ileya

Àkọlé fídíò, Eld Kabir in Nigeria: Mùṣùlùmí àti Kristiẹni sọ̀rọ̀ nípa àdun oúnjẹ́ àti ẹran ọdún Ileya

Loni ọjọ Ẹti ni ayajọ ọdun Ileya fun tọdun yii taa mọ si Eid Kabril.

Gẹgẹ bẹẹ se mọ pe awọn ọmọde ati agba maa n foju sọna fun ọdun alarinrin yii nitori awọn adun kan to wa ninu rẹ.

Idi ree ti BBC Yoruba fi gbe igbimọ kan kalẹ ninu eyi ta ti ri awọn musulumi ati Kristiẹni, ti wọn ti jiroro nipa awọn adun to wa ninu ọdun Ileya.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Lara ohun ti wọn mẹnuba ni ẹran dindin, ounjẹ ọdun, owo ọdun ati asọ ọdun.

Bakan naa ni igbimọ yii tun mẹnuba bi ọdun Ileya se maa n larinrin lasiko igba ti wọn wa ni ewe atawọn ọna ti wsn n gba gbadun rẹ.