Coronavirus recovery cases: Ìrírí ọkùnrin kan tó ní àrùn coronavirus ní ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì rèé

Àkọlé fídíò, Coronavirus cases in Nigeria: Àrùn coronavirus burú gan ni, èmi ò gbàdúrà rẹ̀ fún ọ̀tá mi-

Wọn ni iku to ba fẹ pa ni, to ba ṣi ni ni fila, ọpẹ lo yẹ ki ẹda o da si Eleduwa.

Eyi gan ni ni orin ti alagba, ẹni to ru arun coronavirus la lorilẹede Gẹẹsi.

O ni bi ere bi ere larun naa bẹrẹ ati pe awọn egbo ibilẹ bii galiiki ati nnkan miran ti iyawo oun se foun ati ẹbi oun kun ara ohun to mu ki ara oun tete bọ sipo.