Coronavirus: BBC News Yorùbá ní kí ẹ dúró nílé bí ẹ kò bá ní ìdí láti jáde
Lasiko ti a wa yii, asiko ẹlẹgẹ ati ikiyesara gidi ni.
Bi a ba tẹle awọn imọran gbogbo tawọn onimọ n fi sita a o laa ja.
Idunnu wa ni ileeṣẹ BBC News kaakiri agbaye ni pe ki a ka iye awọn eeyan to laa ja lẹyin ọwọja ajakalẹ arun yii, ki gbogbo ẹyin ololufẹ wa si dahun orukọ yin.
Ẹ wo fidio yii gẹgẹ bi ẹbun kekere ti a ni fun un yin.
- 'Ìnira ńlá ni coronavirus mú bá èmi àtàwọn ọmọ mi gẹ́gẹ́bí opó tó fọ́jú'
- Ọ̀rẹ́ mi ni Kẹ́hìndé Ayọ̀ọlá tó kú, olùfọkànsìn ńlá ni-Ṣeyi Makinde
- Àwọn ohun èèlò tí Olóògbé Olóyè Obafemi Awọ́lọ́wọ̀ lò gbẹ́yìn
- Dòkítà tó ṣe iṣẹ́ abẹ fún oyún inú l‘Amẹrika ló ń sọ Yorùbá yìí, bíi ẹní la oyin
- Ìgunnukó nìyí, òrìsà Tápà, òrìsà olówó àti tọlọ́mọ
- 'Pọ́ńbélé Yorùbá ni mí, n ò sì ní tijú rẹ níbikíbi'
- Itan omi gbigbona ati tutu ni Ikọgosi Ekiti
- Àlàyé rèé lóríi ìdí tí wọ́n fi ń pe aya ní ìyàwó