Obafemi Awolowo: Ọkọ̀ Awólọ́wọ̀ yìí ti lọ yíká Nàíjíríà

Àkọlé fídíò, Ọkọ̀ Awólọ́wọ̀ yìí ti lọ yíká Nàíjíríà

Lẹ́nu àbẹ̀wò BBC Yorùbá sí ilé Awólọ́wọ̀ ní Ìkẹ́nnẹ́, ni ipinlẹ Ogun to wa ni iwọ oorun guusu orilẹ-ede Naijiria a rí asọ tó kú sínú rẹ̀

Koda, a tun ri awò ojú rẹ̀, aago ọwọ́, owó ẹyọ àti owó bébà àtijọ́ tó ná kù, tó fi mọ́ ọkọ̀ tó fi lọ yíká Nàíjíríà láti se ìpolongo ìbò ààrẹ ní ọdún 1979 àti 1983.

Eyi ni BBC Yoruba ẹ ki awọn ewe iwòyí lé mọ sii ni pa akọni ninu itan iran Yoruba ṣaaju ominira Naijiria lọdun 1960.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: