Coronavirus: Opó afọ́jú kan sọ̀rọ̀ lórí ìnira tó ń kojú pẹ̀lúu coronavirus
Kii ṣe asọdun bi a ba wi pe ipenija nla ni asiko ajakalẹ arun coronavirus yii ti mu jade fun gbogbo mutumuwa.
Bi ẹlẹṣin ṣe n sunkun airilẹ fi ẹṣin rin lalaṣọ naa n pariwo airi ode fi lọ.
Bi oniṣẹ ṣe n pariwo araaye lọ ṣiṣẹ pawo sinu aṣuwọn lalainiṣẹ naa n pariwo airaye kaakiri ibi ati waṣẹ oojọ lọ.
Nitori naa ko sẹni ti yoo gbọ ọrs ti opobinrin Moninuọla Ọpẹbiyi ba BBC News Yoruba sọ ti ko ni baa kẹdun.
Gba mu ko tan iba, ẹ jẹ ka jọ wo fidio naa.