Obasanjo: Má a fi ìyókù ayé mi san oore Ọlọ́run ni
Oloye Ọbasanjọ, gẹgẹ bi ara eto fun ayẹyẹ ọjọ ibi ọdun kẹtalelọgọrin rẹ lewaju awọn eekan lọ sibi apejẹ pataki kan fun awọn alejo gbogbo.
Oloye Ọbasanjọ pe ẹni ọdun mẹtalelọgọrin ni ọjọ karun oṣu kẹta lẹyin ti wọn bii ni ọjọ karun oṣu kẹta ọdun 2020.
- Odunlade fẹ́ j'ọba, Bolanle Ninalowo fun ìyàwó rẹ̀ ni ẹ̀bun kanka, Pá Kasumu rebi àgbà ree
- Ilé ẹjọ jú akọwe kọotù tẹ́lẹ̀ri sẹwọ̀n ọdun márùn
- Ènìyàn lásán ní ọba ilẹ̀ Yoruba tí kò bá ṣe ètùtù, ẹ má tẹ ìṣẹ̀ṣe mọ́lẹ̀ - Elebuibon
- Ìpínlẹ̀ Eko kéde afurasí mẹ́ta míràn tó ṣeéṣe kó ni Coronavirus
- Ọ́lọ́pàá bá aṣọ, bàtà àti fóónù ọkùnrin tó dàwátì nílé Pásítọ̀ etí òkun l‘Eko
- Coronavirus ṣe bẹbẹ! Ìrun àpapọ̀ dèèwọ̀ lọ́jọ́ Jímọ̀, kò sí oúnjẹ alẹ́ Olúwa mọ́ fún Kristiẹni
Odu ni oloye Ọbasanjọ lẹka oṣelu nilẹ Naijiria ati lagbaye eyi lo si sọ ile rẹ di ibudo ati gba imọran fun olukuluku awọn eekan ati aṣiwaju ilu gbogbo kaakiri orilẹede agbaye.
Oloye Ọbasanjọ jẹ atapatadide ti Eduwa fun laaye lati darapọ mọ ileeṣẹ ọmọogun Naijiria. Kẹrẹkẹrẹ o di Ọgagun agba, o di olori iṣejọba ologun lọdun 1976. Oun si ni olori ologun akọkọ nilẹ afirika ti yoo finufindọ gbe ijsba silẹ fun alagbada lọdun 1979.
- Èèyàn burúkú l'Ọbasanjọ, rárá ọmọ Nàìjíríà rere ni, àwọn ọmọ Ogun sọ̀rọ̀ nípa Ọbasanjọ
- Ìpínlẹ̀ Ogun fẹ́ fi òfin wọ́gilé ìsìnkú ọba lọ́nà ìṣẹ̀mbáyé
- Ìtan ìgbé ayé Olusegun Obasanjo kọ́ wa nípa sùúrù atápáta-dìde
- Eyín mi ló lágbára jù ní Afíríkà, mò ń fi eyín gbé àpò ìrẹsì, símẹ́ńtì àti jẹnẹrátọ̀ - Taju eléyín idán
- Làá hàn mí dé, ètò tó ń ṣàlàyé ohun tó yẹ ká ṣe láti dènà àrùn Coronavirus
Baba, gẹgẹ bi ọpọlọpọ ṣe maa n pee, bọ si agbo oṣelu lọdun 1998 lẹyin to ti ọgba ẹwọn ti ijọba ologun labẹ Ọgagun Sani Abacha ran an lọ, de.
Lọdun 1999 ni Ọbasanjọ di aarẹ alagbada keji lorilẹ€de Naijiria, ki awọn ọmọ Naijiria to tun yan an si ipo naa fun saa keji lọdun 2003.
Producer: Damilola Oduolowu àti Olumide Owaduge