PDP: Buhari, O ṣeé dá pẹlú bí ko ṣé sọ̀rọ̀ nípa Coronavirus

Aworan aarẹ Buhari

Oríṣun àwòrán, Pius Utomi Ekpei

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Ẹgbẹ oṣelu alatako lorileede Naijiria Peoples Democratic Party ti bẹnu atẹ lu aarẹ Muhamadu Buhari pẹlu bi ko tiṣe ti sọrọ nipa aisan Corona Virus to wọ Naijiria.

Akọwe ipolongo ẹgbẹ naa, Kola Olongbondiyan ni aifini peni, aifeeyan peeyan ni iwa yi jẹ bi aarẹ ko ti ṣe ti ba awọn ọmọ Naijiria sọrọ.

Ninu atẹjade to fi sita loju opo Twitter ẹgbẹ naa, Ologbondiyan ni ijakulẹ lọwọ aṣaaju gba ni o jẹ bi aarẹ ti ṣe dakẹ lori ọrọ yi.

''Ẹgbẹ PDP parọwa si aarẹ lati taji ki o si mu ọrọ CoronaVirus yi bo ti ṣe yẹ nitori ewu nla lo n bọ yi to gba ki aarẹ doju ija kọ''

Ologbondiyan fi kun ọrọ rẹ pe ti aarẹ ba ba awọn ọmọ Naijiria sọrọ, yoo fi ọkan ọpọ eeyan balẹ.

Loju opo Twitter aarẹ Buhari lootọ, ko ti si ọrọ to ni ṣe pẹlu aisan Corona Virus yi ṣugbọnagbẹnusọ ileeṣẹ aarẹ Garba Shehu ni tiẹ da si ọrọ yi.

Ninu ọrọ rẹ, Garba Shehu ṣemọ bi awọn iwe iroyin Naijiria ti ṣe mu ọrọ Coronavirus nikan bẹnu nigba ti aisan iba n gbẹmi ọpọ eeyan lojumọ ni Naijiria.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Ọrọ rẹ yi mu esi orisirisi wa lati ọdọ awọn ọmọ Naijiria

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 2

Skip X post, 3

End of X post, 3

Skip X post, 4

End of X post, 4