Ibadan Fire: Iná míràn tún ṣẹyọ nilú Ibadan

Ile to jo

Oríṣun àwòrán, Magik

Àkọlé àwòrán, Iná míràn tún ṣẹyọ nilú Ibadan

Ilé ìwòsàn kàn ti wọ́n n pe ni Sanwo ni oríta Challenge ni Ibadan ló sàdédé gbina lọ́sàn òní.

Ìròyìn sọ pé iná mọ̀nàmọnána ti wọ́n múlọmúbọ̀ ló fa iná náà, ti wọ́n si ru ẹbi náà ru àwọn ilé iṣẹ́ mọ̀nàmọ̀ná

Ẹni ti ọ̀rọ̀ náà sojú rẹ̀ sàlàyé pé wọ́n ránṣẹ́ pe panápana, sùgbọ́n wọ́n ni ko sí omi ti wọ́n yóò fi pa iná nígbà ti wọ́n de wọ́n ní kò si.

Àkọlé fídíò, Ibadan Fire: Iná míràn tún ṣẹyọ nilú Ibadan

A sì ń ko iròyìn yìí jọ lọ́wọ́